Skip to content

Yoruba past questions: WAEC SSCE 2018

49 objective questions, with answers. Free to read and practise.

Sit this paper

49 questions, one at a time, marked as you go or at the end. No account needed.

  1. 1.
    —— ni iyá Şàngó ni féràn jů
    1. A.Oba
    2. B.Oya
    3. C.Oşun
    4. D.Torosí
    Show answer

    Answer: B Oya

  2. 2.
    [ c a-sunşu-ję ]
    1. A.asun-işu-ję
    2. B.a-sun-işu-je
    3. C.asun-şuję
    Show answer

    Answer: C asun-şuję

  3. 3.
    [ c fi orò lọ iyàwỏ ]
    1. A.mú inú Şàngó bàjé
    2. B.di odò
    3. C.ń yọ iná lénu
    Show answer

    Answer: A mú inú Şàngó bàjé

  4. 4.
    [see linked page: question refers to shared diagram/text above]
    1. A.tónítóní
    2. B.nini
    3. C.fòò
    4. D.láú
    Show answer

    Answer: C fòò

  5. 5.
    Akóbí idíle yíí ni ó di.
    1. A.onímo,ero
    2. B.nóòsi
    3. C.oníşègun
    4. D.tisà
    Show answer

    Answer: A onímo,ero

  6. 6.
    ÀRÒKO Déèti kíko pọn dandan nínú àröko
    1. A.onilétà
    2. B.oníròyin
    3. C.aşàríyànjiyàn
    4. D.aşàpėjúwe
    Show answer

    Answer: A onilétà

  7. 7.
    ÀŞÀ — ni à ń pe omo tí ó wà nínú àpò nígbà tía bí
    1. A.òní
    2. B.Ìgè
    3. C.Ìlộrí
    4. D.Òké
    Show answer

    Answer: D Òké

  8. 8.
    ÀŞÀ —ni Yorùbá gbàgbó pé ó máa ń gbé ire ko ni.
    1. A.owó
    2. B.enu
    3. C.orí
    4. D.esè
    Show answer

    Answer: C orí

  9. 9.
    ÀŞÀ "Ògídiolú oníkànga àjípọn", jé ara oriki.
    1. A.Igè
    2. B.Ìdòwú
    3. C.Öjó
    4. D.Ājàyí
    Show answer

    Answer: D Ājàyí

  10. 10.
    ÀŞÀ Awo rirán jệ isệ.
    1. A.onísònà
    2. B.àyàn
    3. C.olóólà
    4. D.àgbèdę
    Show answer

    Answer: A onísònà

  11. 11.
    ÀŞÀ İkòri jé orişíí
    1. A.filà
    2. B.ilėkè
    3. C.èwù
    4. D.bàtà
    Show answer

    Answer: B ilėkè

  12. 12.
    ÀŞÀ Okét éje èèwò fún iran.
    1. A.Olówu
    2. B.Olúfe
    3. C.Opómúléró
    4. D.Onikoyi
    Show answer

    Answer: D Onikoyi

  13. 13.
    ÀŞÀ Onígbàjámo ni ó máa ń.
    1. A.di irun
    2. B.fá irun
    3. C.lu ilù
    4. D.rọ okó
    Show answer

    Answer: B fá irun

  14. 14.
    ÀŞÀ Orúko miiràn fún "yánko" ni.
    1. A.ètů
    2. B.àdi
    3. C.eyin
    4. D.aró,
    Show answer

    Answer: B àdi

  15. 15.
    Do not cry over spilt milk.
    1. A.má sunkún lórí mílîki tó dànù
    2. B.má bara jé lórí mílfiki tó danu
    3. C.má bara je lórí ohun tí ko ní åtúnse
    4. D.má so irètí nù lórí ohun tí kò tí i bàje
    Show answer

    Answer: C má bara je lórí ohun tí ko ní åtúnse

  16. 16.
    ERÉ ONÍTÀN: Adéríbigbé, M.: Oré Mi "Òdòdó abèmí" wo ni ebí Olápeléke wá lọ sí idilé Egbédá ?
    1. A.Şadé
    2. B.Fikémi
    3. C.Kúnbi
    4. D.Şoláyídé
    Show answer

    Answer: D Şoláyídé

  17. 17.
    ERÉ ONÍTÀN: Adéríbigbé, M.: Oré Mi Ibo ni bàbá Şolá ti ń şişé?
    1. A.ilé-işé işokò
    2. B.ởgbà itókòşe
    3. C.ogbà Yunifásíti
    4. D.réluwèé
    Show answer

    Answer: D réluwèé

  18. 18.
    ERÉ ONÍTÀN: Adéríbigbé, M.: Oré Mi Olóyè Odùnowó ni ó tún ń jé.
    1. A.Tẹjúmówó
    2. B.Káyodé
    3. C.Olápeléke
    4. D.Kólá
    Show answer

    Answer: C Olápeléke

  19. 19.
    ERÉ-ONÍŞE: Àjùwòn, B: Irèmòjé Eré Isipà ode Omisin Ogún ni à ń pè ní.
    1. A.Alukósó
    2. B.Alágùnta
    3. C.Alůlégò
    4. D.Alàwòrò
    Show answer

    Answer: C Alůlégò

  20. 20.
    ERÉ-ONÍŞE: Àjùwòn, B: Irèmòjé Eré Isipà ode Òrişà wo ni ó ni Irèmòjé?
    1. A.Obàtálá
    2. B.Ogún
    3. C.Eşù
    4. D.Şàngó
    Show answer

    Answer: B Ogún

  21. 21.
    ERÉ-ONÍŞE: Àjùwòn, B: Irèmòjé Eré Isipà ode Òru ni a mảa ń.
    1. A.sipà ode
    2. B.sàríyå odę
    3. C.sin ode
    4. D.dègbé ode
    Show answer

    Answer: A sipà ode

  22. 22.
    ÈTÒ ÌRÓ Èwo ni ó lè so iró di aránmúpė?
    1. A.àjà enu
    2. B.òlélé
    3. C.tán-án-ná
    4. D.àfàsé
    Show answer

    Answer: D àfàsé

  23. 23.
    ÈTÒ ÌRÓ Fáwẹ̀lì aránmúpẹ̀, àyanudìẹ̀pẹ̀, robọ́tò ni.
    1. A.[ɛ̃]
    2. B.[ɔ̃]
    3. C.[ĩ]
    4. D.[ã]
    Show answer

    Answer: B [ɔ̃]

  24. 24.
    ÈTÒ ÌRÓ Kóńsónàhtì àfàfàşé pé ni
    1. A.[K ]
    2. B.[f]
    3. C.[t]
    4. D.[s]
    Show answer

    Answer: A [K ]

  25. 25.
    ÈTÒ ÌRÓ Olóòót6' jé òrò onísilébù
    1. A.méje
    2. B.méta
    3. C.márùn-ún
    4. D.merin
    Show answer

    Answer: C márùn-ún

  26. 26.
    Ewi: Babalolá, A.: Àwon orikì oríle métàdínlógbòn (pp.iii-116) İyá Alááfin òpómúléró ni.
    1. A.İwànù omọ pa- wón-dà
    2. B.Morejè n'Murệ
    3. C.Obàrànbirí
    4. D.Móríléwá
    Show answer

    Answer: B Morejè n'Murệ

  27. 27.
    Ewi: Babalolá, A.: Àwon orikì oríle métàdínlógbòn (pp.iii-116) Nínú oriki "Ìran opómúléró", ta ni ó lọ sógun tí kò padà mộ? .
    1. A.Abímbéşú ,
    2. B.Afibirin
    3. C.Àbídòrí
    4. D.Àfonjá. ,
    Show answer

    Answer: D Àfonjá. ,

  28. 28.
    EWI: Fádíyà, 0.: tyá Ảtảtà Kí ni ó ń fa eni lé ikú àitójó lówó?
    1. A.owó òkùnkùn
    2. B.işé òkùnkùn
    3. C.ọmọ eríwo
    4. D.iràwò àsán
    Show answer

    Answer: A owó òkùnkùn

  29. 29.
    EWI: Fádíyà, 0.: tyá Ảtảtà Nínú ewi "Obìnrin Ológo", oba àwon ęja ni.
    1. A.Agùalà
    2. B.Àkárákudà
    3. C.Qrí
    4. D.Òjí
    Show answer

    Answer: D Òjí

  30. 30.
    EWI: Fádíyà, 0.: tyá Ảtảtà Ta ni olórí egbé òkùnkùn àkókó?
    1. A.Lúsíféri
    2. B.Āpáta páàrá
    3. C.ipánre
    4. D.jàndùkú
    Show answer

    Answer: A Lúsíféri

  31. 31.
    GİRÁMÀ Nínú "Dipò rí mi lánàá" a lo 'mi' gégé bí orò arópò orúko.
    1. A.eni kiiní, eyo, nípò olùwà
    2. B.eni kiiní, opo, nípò olùwà
    3. C.eni kiní, eyo, nípò àbo
    4. D.eni kiní, opo, nípò àbo
    Show answer

    Answer: C eni kiní, eyo, nípò àbo

  32. 32.
    GİRÁMÀ Nínú "orò náà kò şe é gbó séti"a lo 'naa' gégé bí èyán.
    1. A.aşàfihàn
    2. B.ajórúkọ
    3. C.aşàpėjúwe
    4. D.asònkà
    Show answer

    Answer: A aşàfihàn

  33. 33.
    İmòràn tí a fún Şàngó ni pé kí ó
    1. A.pa àwon jagunjagun
    2. B.fa ojú àwon jagungun móra
    3. C.din inú bibí re kù
    4. D.sóra fun àwon iyàwó re
    Show answer

    Answer: A pa àwon jagunjagun

  34. 34.
    İTúmo okookan gbólóhùn tí ó wà ibéèrè yii si èdė Yorůbá. It serves you right.
    1. A.ó şe o dáadáa
    2. B.ó tójú rẹ tó
    3. C.ohun ojú wá lójú ri
    4. D.ó pèsè ohun dídára fún o
    Show answer

    Answer: C ohun ojú wá lójú ri

  35. 35.
    Ka àyokà isàlè wònyii, kí o sì dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkòòkan won. İtàn àbláyé so pé Oba ni Şàngó lóde Oyó nígbà ayé rè. Omo İlú Tápà ti Elénpe ni Torosí iyá rè. Àwọn iyàwó métèèta tí Şàngó fé ni wón di odò léyiìn ikú won: Oya bíņú di odo Oya, Obà di odò Obà tí ó la İwổ kòja Sun sì di odò Oşun tí ó la Òsogbo kojá, Aágbára ni Şàngó, ó láyà, ó sì lóògùn débi pé ó máa ń yoná lénu bí inú bá ń bí i, Éyi mủ kí èrù rè máa bá tẹrú tọmọ láşikò náà. lóde Òyó tó, Tìmì Ágbàlé àti Gbòńkáà Ebiri. tí won si jé kí inú Şàngó dun rárá. ó forò náà tó Oya tí ó jé ààyò rè létí. ya si gbà á nímoràn láti wá onà tí yóò fi yęjú àwon méjèèji.he Ohun ti ó mú erù Sàngó bả âwon ará ilú ni pé Ú.
    1. A.fé iyàwó méta
    2. B.jé oba Oyó
    3. C.máa ń yo iná lénu
    4. D.jé omọ Tápå
    Show answer

    Answer: C máa ń yo iná lénu

  36. 36.
    Ka àyokà isàlè wònyii, kí o sì dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkòòkan won. Ojó mánigbàgbé, ojó ayò, lójó ti Adétutù gbé Adéagbo àti Ajibikèé tí wón jé òbí rè lo sí ilú oyinbó. Awon méjèèji si fopé fún Olorun pé àwon ti ipase omọ là. Wón kò bả olá nílé şùgbón èkó àwon omo won je wón lògún Wón tiraka láti rán àwon omo won nílé èko. Âwon omọ náà sì kàwé yanjú. Akíntòmídé, àkóbí won, di ògá onímò èrọ. Adétutů gba oyè imo ijinlè nínú işé iségun: Olúwaşeun di Omowé nínú isé olůkoni. Abiímbolá, àbikéyin won yan işé nóosi láàyò. Oun nikan ni ó ń şişé ní orilè èdè Nàijíríà. Àwon yà yòókù si fi Okè Ökun şe ibùgbé. BÍ Adéagbo àti Ajibíkėé, iyàwó rè şe padà sí orílè èdè Nàijíríà, ilé tí Abímbolá kó fún won ni wón dé sí. Motò obokùn olóyé tí Olúwaşeun rà fún wọn ni ó wá gbé wọn ní pápáko ofurufú. —— ni ó ń şişè ní orile èdè Nåijiriä?
    1. A.Olúwaşeun
    2. B.Akíntomídé
    3. C.Adétutu
    4. D.Abímbolá
    Show answer

    Answer: D Abímbolá

  37. 37.
    LÍTÍRÉŞO - OGBÓ N - İTOPINPIN LÍTÉRÉŞO "Álírá lóra rélá" jé àpęệrę .
    1. A.aló āpamò
    2. B.oriki
    3. C.orò akónilénu
    4. D.ofo
    Show answer

    Answer: C orò akónilénu

  38. 38.
    LÍTÍRÉŞO - OGBÓ N - İTOPINPIN LÍTÉRÉŞO Èwo ni ó jé ikíni ?
    1. A.igbà á ro
    2. B.má şe fîrú foná
    3. C.ojú ló mọ ohun to yonu y8
    4. D.måá gbéná wojú rẹ
    Show answer

    Answer: A igbà á ro

  39. 39.
    LÍTÍRÉŞO - OGBÓ N - İTOPINPIN LÍTÉRÉŞO Parí òwe yií: "Láiku Èkiri, enikan kò lè— " .
    1. A.yájú sí i
    2. B.fawo rè şe gbedu
    3. C.fawo rè şeré
    4. D.gbéná wojú rè
    Show answer

    Answer: B fawo rè şe gbedu

  40. 40.
    LÍTÍRÉŞO ALOHÙN -İTÀN ÀRÒSO Àmoó, A.: Àkójopò Àló Åpagbè Kí ni oba şe fún eni tí ó pa Abuké Oşin?
    1. A.ó pa á
    2. B.ó sọ ó doré kòríkòsùn
    3. C.ó dá a lóla
    4. D.ó fún un ní eşin ńlá kan
    Show answer

    Answer: C ó dá a lóla

  41. 41.
    LÍTÍRÉŞO ALOHÙN -İTÀN ÀRÒSO Àmoó, A.: Àkójopò Àló Åpagbè Nínú "ijapá àti Ajá", ta ni ó pa Abuké Oşin?
    1. A.Oba
    2. B.igbín
    3. C.onilù
    4. D.ijàpá
    Show answer

    Answer: B igbín

  42. 42.
    LÍTÍRÉŞO ALOHÙN -İTÀN ÀRÒSO Àmoó, A.: Àkójopò Àló Åpagbè Nínú itàn "ilệ àti Olórun", ta ni ó gbé èbọ lọ sorun?
    1. A.babaláwo
    2. B.Oba
    3. C.eyę iğún
    4. D.eku emó
    Show answer

    Answer: C eyę iğún

  43. 43.
    LÍTÍRÉŞO ẢPILĘKO - İTÀN ÀRÒSO Ajéwolé, 0.: Igbèyin Laláyò Ń Ta Ibo ni gbómogbómo ti gbé Obí?
    1. A.Ībàdàn
    2. B.İşéyin
    3. C.İjerò
    4. D.Ikóro
    Show answer

    Answer: A Ībàdàn

  44. 44.
    LÍTÍRÉŞO ẢPILĘKO - İTÀN ÀRÒSO Ajéwolé, 0.: Igbèyin Laláyò Ń Ta İyàwó mélòó ni bàbá Òbíşèsan ní?
    1. A.méfà
    2. B.mérin
    3. C.méta
    4. D.méji
    Show answer

    Answer: D méji

  45. 45.
    LÍTÍRÉŞO ẢPILĘKO - İTÀN ÀRÒSO Ajéwolé, 0.: Igbèyin Laláyò Ń Ta Ta ni "omo Oré-Ewi"?
    1. A.İyá Òbí
    2. B.ègbón Òbí
    3. C.Bàbá Òbí
    4. D.òré Òbí
    Show answer

    Answer: C Bàbá Òbí

  46. 46.
    Orúko iyá Şàngó ni [ b oya ]
    1. A.Oşun
    2. B.Eléńpe
    3. D.Torosí
    Show answer

    Answer: D Torosí

  47. 47.
    Sadé is the apple of her father's eyes.
    1. A.Şadé jé aşojú bàbá re
    2. B.Şadé jè eyin-lójú bàbá rè
    3. C.Şadé jė ápù bàbả rè
    4. D.Bàbá Şadé jè ápù rè
    Show answer

    Answer: B Şadé jè eyin-lójú bàbá rè

  48. 48.
    Şolá visits once in a blue moon.
    1. A.Solá ń şàbèwò lópò igbà
    2. B.Şolá lè şàbèwò bóşůpá bá yọ
    3. C.Şolá ń şàbèwò léékòòkan
    4. D.Şọlả máa ń șàbèwò nínú òşupá
    Show answer

    Answer: C Şolá ń şàbèwò léékòòkan

  49. 49.
    Traka nínú àyòká yií túmo sí
    1. A.rin irinàjò
    2. B.fi opé fún Olórun
    3. C.gbiyànjú
    4. D.ramotò
    Show answer

    Answer: A rin irinàjò

Printing is turned off here to protect the question bank. Get the SmarTest app to study offline.

More free Yoruba papers

WAEC Yoruba 2008–2014 is in the app

The latest five years of each paper are free here. The SmarTest app has every year we hold, a worked explanation for each answer, and timed mock exams. It works offline.

Get the app

Android, Windows, Mac and Linux