Yoruba past questions: WAEC SSCE 2025
44 objective questions, with answers. Free to read and practise.
Sit this paper
44 questions, one at a time, marked as you go or at the end. No account needed.
- 1....jẹ́ ọ̀kan lára oríṣi afipẹ̀ tí ó wà:
- A.Aìkúnyùn
- B.Akànmọlẹ̀
- C.Àṣẹ̀sì
- D.Áṣéṣetán
Show answerHide answer
Answer: B Akànmọlẹ̀
- 2."Aṣọ òkè di aṣọòkè" nípasẹ̀ ìgbésẹ̀...
- A.ìyọ̀pọ̀ fáwẹ́lì
- B.ipàjẹ
- C.àńkọ̀ọ́ fáwẹ́lì
- D.àránmọ̀
Show answerHide answer
Answer: B ipàjẹ
- 3.[see linked page: question refers to shared diagram/text above]
- A.ayẹsí
- B.idánwò
- C.ìròyìn
- D.ìràsílẹ̀
Show answerHide answer
Answer: A ayẹsí
- 4.Afẹ̀nilọ́bìnrin kò fojú ire wò ní" jẹ́ àpẹẹrẹ
- A.Òríkì
- B.Aló
- C.Ìwúre
- D.Òwè
Show answerHide answer
Answer: D Òwè
- 5.Ajíṣefìnì' jẹ́ àpẹrẹ orúkọ
- A.abíkú
- B.àmútorunwá
- C.àbísọ
- D.ilaje
Show answerHide answer
Answer: D ilaje
- 6.Àpẹẹrẹ àṣọ̀régéé ni
- A.Ikú ogun ni í pa akínkanjú
- B.Ẹni tí kò rọmọ bí yóò dọlómọ
- C.Léyìn ogun, ẹyẹ làsán kò fò ní ilú náà
- D.Ọmọ òpó koobiti koobiti
Show answerHide answer
Answer: C Léyìn ogun, ẹyẹ làsán kò fò ní ilú náà
- 7.Àwọn tí ó ń jagun fún ìlú ni a ń pè ní
- A.esó
- B.ilari
- C.ẹrú
- D.ìwọ̀fà
Show answerHide answer
Answer: A esó
- 8.Bàbá Adió ni ó
- A.ká Oládéjọ mọ́ ilé Adió
- B.rà ọjà àwìn lọ́wọ́ Adíjá
- C.fowó taaká lójú àgbo
- D.tẹ̀lé ọkọ lọ sí Kútònù
Show answerHide answer
Answer: C fowó taaká lójú àgbo
- 9.ÈGÈ, ÈRÉ ONÍṢE - RAJI, S.: Ẹ̀gẹ̀ Dídá Ẹ̀gẹ̀ dídá fi ara pé
- A.Èṣù pípè
- B.ekún iyàwó
- C.orin obìtùn
- D.orin etiyèrí
Show answerHide answer
Answer: A Èṣù pípè
- 10.ÈGÈ, ÈRÉ ONÍṢE - RAJI, S.: Ẹ̀gẹ̀ DídáÌjora tí ó wà láàrin ẹ̀gẹ̀ dídá àti rárá sísùn ni pé
- A.ohùn kan náà ni wọn ń lò fún àwọn méjèèjì
- B.àdúgbò kan náà ni àwọn méjèèjì ti ń wáyé
- C.a ń fi rárá kì Ọba; a ń fi ẹ̀gẹ̀ náà kì Ọba
- D.àwọn olórò ló ní àwọn méjèèjì
Show answerHide answer
Answer: C a ń fi rárá kì Ọba; a ń fi ẹ̀gẹ̀ náà kì Ọba
- 11.Èwo ni a máa ń lò láti fi kí ẹni tí a kọ lẹ́tà àìgbagbefẹ́ sí?
- A.Orúkọ àbísọ rẹ
- B.Orúkọ ipò rẹ
- C.Àwọn inágijẹ rẹ
- D.Òríkì orílẹ̀ rẹ
Show answerHide answer
Answer: B Orúkọ ipò rẹ
- 12.Èwo ni ó ga jù nínú ìgbàgbọ́ Yorùbá?
- A.Ọba
- B.Ọkú-òrùn
- C.Olódùmarè
- D.Ọ̀rìṣà
Show answerHide answer
Answer: C Olódùmarè
- 13.Èwo ni ó jẹ́ yọ nínú ayọ̀lọ́ yìí: "Ọmọ ejò méta; okan n bẹ̀ nídìí ọpẹ, ọ̀kan ń bẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ̀ ọpẹ, ọ̀kan ń bẹ̀ lórí ọpẹ"?
- A.Ẹdá-ọrọ
- B.Awítúnwí
- C.Ifọ̀ròdára
- D.Àfíwẹ̀
Show answerHide answer
Answer: B Awítúnwí
- 14.Èwo ni owe tí Àdán pa nínú àló "Ìjàpá lo jẹ àsè ní ilé Àdán"?
- A.Bí a bá ń sunkún, a máa rí ran
- B.Àtigùn là á kọ́ ọmọde, a kì í kọ ní àtisọ́
- C.Agbà tí kò lẹsẹ̀ ńlẹ̀, ò lógbón lórí
- D.Ọ̀nà dé orí ọpẹ ò pin
Show answerHide answer
Answer: B Àtigùn là á kọ́ ọmọde, a kì í kọ ní àtisọ́
- 15.Èyí tí ó jẹ́ mọ́ ọrọ̀-aje nínú àṣà ìbílẹ̀ ni
- A.opó ṣíṣú
- B.ẹ̀tọ́ ikẹ̀sẹ̀ ayé
- C.ìwọ̀fà yíya
- D.awo Egúngún
Show answerHide answer
Answer: C ìwọ̀fà yíya
- 16.Ìrò fáwẹ́lì àhánupẹ̀ iwájú ni...
- A./o/
- B./e/
- C./ẹ/
- D./a/
Show answerHide answer
Answer: B /e/
- 17.ÌTÚMỌ̀ ÈDÈ: Tumo Geesi yi si Yoruba
- A.Ó wà ní etí odò
- B.Ó wà ní ibi tí a gbé omi pamọ́ sí
- C.Ó wà ní inú odò
- D.Ó wà ní ibi tí ó tin dé odò
Show answerHide answer
Answer: A Ó wà ní etí odò
- 18.ÌTÚMỌ̀ ÈDÈ: Tumo Geesi yi si Yoruba"It is a case of pot calling the kettle black."
- A.Ọ̀jọ̀ gbogbo ni tòlé, ọjọ́ kan ni tòlóhun.
- B.Ìkòkò dúdú tí dì bọ́gbẹ́.
- C.Ṣágo ń bú igò.
- D.Afáráwẹ̀ kò dára.
Show answerHide answer
Answer: C Ṣágo ń bú igò.
- 19.ÌTÚMỌ̀ ÈDÈ: Tumo Geesi yi si Yoruba"No substitute equals the original."
- A.Odò tó tọjú ẹni kún, kì í gbéni lọ.
- B.Ẹ fi eléyìí tí kò tó rọ́pò rẹ̀.
- C.Ojú afòó fọ́tán, ìjà ní í dá sílẹ̀.
- D.Ojù méwaá kò jó ojú ẹni.
Show answerHide answer
Answer: D Ojù méwaá kò jó ojú ẹni.
- 20.ÌTÚMỌ̀ ÈDÈ: Tumo Geesi yi si Yoruba"You do not take serious issues with levity."
- A.A kì í fojú bọ̀rọ̀ gbọ́mọ lọ́wọ́ ẹ̀kùrọ́
- B.A k i fi oro pataki fale
- C.Ọ̀rọ̀ kò ní tóbi ká fi obẹ̀ bù ú
- D.A kì í dàgbà màá ní aya
Show answerHide answer
Answer: B A k i fi oro pataki fale
- 21.Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti o wa nibe. Ka àwọn ayokà ìsalę winyi ki o si dáhùn àwọn ìbéèrè tíó tělé okookan wọn. Orişií àwọ méfa ni oluko wa ko wa bí a şe ń po àwọ mìíràn pò mộ ara wọn láti șědá wọn. Àwọ kin-ín-ní ti wọn ko wa bí wọn şe n sędá rẻ ni sán-án-yán, ekeji ni ofèéfèé, ękęta ni àwọ ewé, ękęrin ni àwò eérú, ekarùn-ún ni àwọ gbúre nígbà tí ękęta jé àwọ omi osản. A ó mú àwọn àwò náà ní șísę-n-tělé láti șàlàyé bí wọn şe n şędá wọn. Àwọ méta ni a popò láti șędá àwọ kìn-in-ní, àwọn àwọ tí a pò pò náà ni àwò aró, pupa àti òfeéféé. Ní ti àwọ kejì, a po àwò pupa pọ mọ àwọ ewé. Ní ti ękęta, a po àwọ òfeéfèé mó àwọ aró. Ní ti àwọ kẹrin, a po àwọ dúdú pộ mó funfun. Ní ti àwọ karùn-ún, a po àwọ pupa mọ funfun. Ní ti ękęfà, a wáá po àwò pupa mó òfèéfèé. Bí ìdánilékỳó wa lórí oríşirişi àwọ àti ộnà tí à ígbà şędá wọn șe lọ ní ọjọ náà nìyện. Àwọ̀ tí a lò lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo ni
- A.Dúdú
- B.Pupa
- C.Òfèéfèé
- D.Aro
Show answerHide answer
Answer: A Dúdú
- 22.Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti o wa nibe. Ka àwọn ayokà ìsalę winyi ki o si dáhùn àwọn ìbéèrè tíó tělé okookan wọn. Orişií àwọ méfa ni oluko wa ko wa bí a şe ń po àwọ mìíràn pò mộ ara wọn láti șědá wọn. Àwọ kin-ín-ní ti wọn ko wa bí wọn şe n sędá rẻ ni sán-án-yán, ekeji ni ofèéfèé, ękęta ni àwọ ewé, ękęrin ni àwò eérú, ekarùn-ún ni àwọ gbúre nígbà tí ękęta jé àwọ omi osản. A ó mú àwọn àwò náà ní șísę-n-tělé láti șàlàyé bí wọn şe n şędá wọn. Àwọ méta ni a popò láti șędá àwọ kìn-in-ní, àwọn àwọ tí a pò pò náà ni àwò aró, pupa àti òfeéféé. Ní ti àwọ kejì, a po àwò pupa pọ mọ àwọ ewé. Ní ti ękęta, a po àwọ òfeéfèé mó àwọ aró. Ní ti àwọ kẹrin, a po àwọ dúdú pộ mó funfun. Ní ti àwọ karùn-ún, a po àwọ pupa mọ funfun. Ní ti ękęfà, a wáá po àwò pupa mó òfèéfèé. Bí ìdánilékỳó wa lórí oríşirişi àwọ àti ộnà tí à ígbà şędá wọn șe lọ ní ọjọ náà nìyện. Àwọ̀ tí a ṣe dá kejì jẹ́
- A.Òfèéfèé
- B.Òmi osàn
- C.Gbúrẹ̀
- D.Sán-án-yán
Show answerHide answer
Answer: A Òfèéfèé
- 23.Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti o wa nibe. Ka àwọn ayokà ìsalę winyi ki o si dáhùn àwọn ìbéèrè tíó tělé okookan wọn. Orişií àwọ méfa ni oluko wa ko wa bí a şe ń po àwọ mìíràn pò mộ ara wọn láti șědá wọn. Àwọ kin-ín-ní ti wọn ko wa bí wọn şe n sędá rẻ ni sán-án-yán, ekeji ni ofèéfèé, ękęta ni àwọ ewé, ękęrin ni àwò eérú, ekarùn-ún ni àwọ gbúre nígbà tí ękęta jé àwọ omi osản. A ó mú àwọn àwò náà ní șísę-n-tělé láti șàlàyé bí wọn şe n şędá wọn. Àwọ méta ni a popò láti șędá àwọ kìn-in-ní, àwọn àwọ tí a pò pò náà ni àwò aró, pupa àti òfeéféé. Ní ti àwọ kejì, a po àwò pupa pọ mọ àwọ ewé. Ní ti ękęta, a po àwọ òfeéfèé mó àwọ aró. Ní ti àwọ kẹrin, a po àwọ dúdú pộ mó funfun. Ní ti àwọ karùn-ún, a po àwọ pupa mọ funfun. Ní ti ękęfà, a wáá po àwò pupa mó òfèéfèé. Bí ìdánilékỳó wa lórí oríşirişi àwọ àti ộnà tí à ígbà şędá wọn șe lọ ní ọjọ náà nìyện. Àwọ̀ wo ni a pọ̀ pọ̀ láti ṣe àwọ̀ òfèéfèé?
- A.Pupa àti ewé
- B.Pupa àti funfun
- C.Èérú àti ewé
- D.Dúdú àti funfun
Show answerHide answer
Answer: A Pupa àti ewé
- 24.Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti o wa nibe. Ka àwọn ayokà ìsalę winyi ki o si dáhùn àwọn ìbéèrè tíó tělé okookan wọn. Orişií àwọ méfa ni oluko wa ko wa bí a şe ń po àwọ mìíràn pò mộ ara wọn láti șědá wọn. Àwọ kin-ín-ní ti wọn ko wa bí wọn şe n sędá rẻ ni sán-án-yán, ekeji ni ofèéfèé, ękęta ni àwọ ewé, ękęrin ni àwò eérú, ekarùn-ún ni àwọ gbúre nígbà tí ękęta jé àwọ omi osản. A ó mú àwọn àwò náà ní șísę-n-tělé láti șàlàyé bí wọn şe n şędá wọn. Àwọ méta ni a popò láti șędá àwọ kìn-in-ní, àwọn àwọ tí a pò pò náà ni àwò aró, pupa àti òfeéféé. Ní ti àwọ kejì, a po àwò pupa pọ mọ àwọ ewé. Ní ti ękęta, a po àwọ òfeéfèé mó àwọ aró. Ní ti àwọ kẹrin, a po àwọ dúdú pộ mó funfun. Ní ti àwọ karùn-ún, a po àwọ pupa mọ funfun. Ní ti ękęfà, a wáá po àwò pupa mó òfèéfèé. Bí ìdánilékỳó wa lórí oríşirişi àwọ àti ộnà tí à ígbà şędá wọn șe lọ ní ọjọ náà nìyện. Èwo ni iye àwọ̀ tí a pọ̀ pọ̀ láti ṣe àwọ̀ pọ̀ jù?
- A.Òfèéfèé
- B.Èérú
- C.Ewé
- D.Sán-án-yán
Show answerHide answer
Answer: D Sán-án-yán
- 25.Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti o wa nibe. Ka àwọn ayokà ìsalę winyi ki o si dáhùn àwọn ìbéèrè tíó tělé okookan wọn. Orişií àwọ méfa ni oluko wa ko wa bí a şe ń po àwọ mìíràn pò mộ ara wọn láti șědá wọn. Àwọ kin-ín-ní ti wọn ko wa bí wọn şe n sędá rẻ ni sán-án-yán, ekeji ni ofèéfèé, ękęta ni àwọ ewé, ękęrin ni àwò eérú, ekarùn-ún ni àwọ gbúre nígbà tí ękęta jé àwọ omi osản. A ó mú àwọn àwò náà ní șísę-n-tělé láti șàlàyé bí wọn şe n şędá wọn. Àwọ méta ni a popò láti șędá àwọ kìn-in-ní, àwọn àwọ tí a pò pò náà ni àwò aró, pupa àti òfeéféé. Ní ti àwọ kejì, a po àwò pupa pọ mọ àwọ ewé. Ní ti ękęta, a po àwọ òfeéfèé mó àwọ aró. Ní ti àwọ kẹrin, a po àwọ dúdú pộ mó funfun. Ní ti àwọ karùn-ún, a po àwọ pupa mọ funfun. Ní ti ękęfà, a wáá po àwò pupa mó òfèéfèé. Bí ìdánilékỳó wa lórí oríşirişi àwọ àti ộnà tí à ígbà şędá wọn șe lọ ní ọjọ náà nìyện. Ìgbà mélòó ni a po àwọ̀ pupa pọ̀ mọ́ àwọ̀ míìrán nínú àyọkà yìí?
- A.Mérin
- B.Márùn-ún
- C.Méfà
- D.Méta
Show answerHide answer
Answer: A Mérin
- 26.Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti otelee. Ni igba kan, ní ilu Ayegbajeje, orúko inagije ni won fi máa ń pe Asá áti Awodi. İkuloogun ni wón máa ń pe Aşá, Iku-wolé-awo ni wớn si máa ń pe Awòdi. Bi wón bá féệ sảlàye nkankan nípa àwọn méjèèji wónyi, wón lè sọ pé órómodiyę, ęyę kéékėčké, eku áti alángbá ni Ikúlóògún máa ń ję. İşépé igi áti įka-igi tí kò gbó ni o fi máa ń şe ité ré si ori ęka-igi tí ó ti gbó. Eyin méta sí mrin ni ó máa ń yẻ. Àwọ funfun tí ó dàbí igbà pé a fi àwọ pupa áti sán-án-yán kùn lára bálabála ni eyin rẻ yii máa ń ní. Tí abo bá sába lórí ęyin yii dię tỉ ở bả dide, ako náà yóò sába lé e. Eyo kookan tàbí méji ni wón máa ń rin. Ikúlóògùn lẻ dúró ní ojú òfurufü fün igbả pípé láijábó. Ni ti Iku-wolé-awo, ó máa ń ję órómodiye, eku, alángbá, ákéré àti esú; ó sì lẻ máa jęun bí ở bá n fô lọ. İtệ rẻ máa ń ga sókè diệ lórí ęka igi nígbả çęrün. Eyin kan sí méta nì ở máa ń yẻ. Ảwợ ewé àti funfun ni eyin yii máa ń nỉ șugbón ảwo pupa tóótòòtó tún máa ń wà lára çyin yii. Ó fi igbe jo igbe ológbò. Ó lẻ då rin, wộn lè rìn ní méjiméji, ní igbà miírăn, àwọn tỉ wón jọ máa ń rìn lè pé igba. Apėjá Ikúlóögùn ni Ikúlóògun-jawo-lọ nígbà tí àpėjá lkú-wolé-awo jé Ikú-wolé-awo-sákálá, ęni-ti-kò-lóbinrin-ana-re-ki-i-kú. Ẹni tí ó le dúró sójú òfurufú fún ìgbà pípẹ̀ ni:
- A.Eku
- B.Àkéré
- C.Aṣá
- D.Awódi
Show answerHide answer
Answer: D Awódi
- 27.Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti otelee. Ni igba kan, ní ilu Ayegbajeje, orúko inagije ni won fi máa ń pe Asá áti Awodi. İkuloogun ni wón máa ń pe Aşá, Iku-wolé-awo ni wớn si máa ń pe Awòdi. Bi wón bá féệ sảlàye nkankan nípa àwọn méjèèji wónyi, wón lè sọ pé órómodiyę, ęyę kéékėčké, eku áti alángbá ni Ikúlóògún máa ń ję. İşépé igi áti įka-igi tí kò gbó ni o fi máa ń şe ité ré si ori ęka-igi tí ó ti gbó. Eyin méta sí mrin ni ó máa ń yẻ. Àwọ funfun tí ó dàbí igbà pé a fi àwọ pupa áti sán-án-yán kùn lára bálabála ni eyin rẻ yii máa ń ní. Tí abo bá sába lórí ęyin yii dię tỉ ở bả dide, ako náà yóò sába lé e. Eyo kookan tàbí méji ni wón máa ń rin. Ikúlóògùn lẻ dúró ní ojú òfurufü fün igbả pípé láijábó. Ni ti Iku-wolé-awo, ó máa ń ję órómodiye, eku, alángbá, ákéré àti esú; ó sì lẻ máa jęun bí ở bá n fô lọ. İtệ rẻ máa ń ga sókè diệ lórí ęka igi nígbả çęrün. Eyin kan sí méta nì ở máa ń yẻ. Ảwợ ewé àti funfun ni eyin yii máa ń nỉ șugbón ảwo pupa tóótòòtó tún máa ń wà lára çyin yii. Ó fi igbe jo igbe ológbò. Ó lẻ då rin, wộn lè rìn ní méjiméji, ní igbà miírăn, àwọn tỉ wón jọ máa ń rìn lè pé igba. Apėjá Ikúlóögùn ni Ikúlóògun-jawo-lọ nígbà tí àpėjá lkú-wolé-awo jé Ikú-wolé-awo-sákálá, ęni-ti-kò-lóbinrin-ana-re-ki-i-kú. Èwo ni èyìn rẹ ní sán-án-yán lára?
- A.Aṣá
- B.Alángbá
- C.Awódi
- D.Òròmodiyẹ
Show answerHide answer
Answer: A Aṣá
- 28.Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti otelee. Ni igba kan, ní ilu Ayegbajeje, orúko inagije ni won fi máa ń pe Asá áti Awodi. İkuloogun ni wón máa ń pe Aşá, Iku-wolé-awo ni wớn si máa ń pe Awòdi. Bi wón bá féệ sảlàye nkankan nípa àwọn méjèèji wónyi, wón lè sọ pé órómodiyę, ęyę kéékėčké, eku áti alángbá ni Ikúlóògún máa ń ję. İşépé igi áti įka-igi tí kò gbó ni o fi máa ń şe ité ré si ori ęka-igi tí ó ti gbó. Eyin méta sí mrin ni ó máa ń yẻ. Àwọ funfun tí ó dàbí igbà pé a fi àwọ pupa áti sán-án-yán kùn lára bálabála ni eyin rẻ yii máa ń ní. Tí abo bá sába lórí ęyin yii dię tỉ ở bả dide, ako náà yóò sába lé e. Eyo kookan tàbí méji ni wón máa ń rin. Ikúlóògùn lẻ dúró ní ojú òfurufü fün igbả pípé láijábó. Ni ti Iku-wolé-awo, ó máa ń ję órómodiye, eku, alángbá, ákéré àti esú; ó sì lẻ máa jęun bí ở bá n fô lọ. İtệ rẻ máa ń ga sókè diệ lórí ęka igi nígbả çęrün. Eyin kan sí méta nì ở máa ń yẻ. Ảwợ ewé àti funfun ni eyin yii máa ń nỉ șugbón ảwo pupa tóótòòtó tún máa ń wà lára çyin yii. Ó fi igbe jo igbe ológbò. Ó lẻ då rin, wộn lè rìn ní méjiméji, ní igbà miírăn, àwọn tỉ wón jọ máa ń rìn lè pé igba. Apėjá Ikúlóögùn ni Ikúlóògun-jawo-lọ nígbà tí àpėjá lkú-wolé-awo jé Ikú-wolé-awo-sákálá, ęni-ti-kò-lóbinrin-ana-re-ki-i-kú. Èwo ni ó ń jẹ esù?
- A.Aṣá
- B.ẹlẹ́là
- C.Awódi
- D.Akéré
Show answerHide answer
Answer: C Awódi
- 29.Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti otelee. Ni igba kan, ní ilu Ayegbajeje, orúko inagije ni won fi máa ń pe Asá áti Awodi. İkuloogun ni wón máa ń pe Aşá, Iku-wolé-awo ni wớn si máa ń pe Awòdi. Bi wón bá féệ sảlàye nkankan nípa àwọn méjèèji wónyi, wón lè sọ pé órómodiyę, ęyę kéékėčké, eku áti alángbá ni Ikúlóògún máa ń ję. İşépé igi áti įka-igi tí kò gbó ni o fi máa ń şe ité ré si ori ęka-igi tí ó ti gbó. Eyin méta sí mrin ni ó máa ń yẻ. Àwọ funfun tí ó dàbí igbà pé a fi àwọ pupa áti sán-án-yán kùn lára bálabála ni eyin rẻ yii máa ń ní. Tí abo bá sába lórí ęyin yii dię tỉ ở bả dide, ako náà yóò sába lé e. Eyo kookan tàbí méji ni wón máa ń rin. Ikúlóògùn lẻ dúró ní ojú òfurufü fün igbả pípé láijábó. Ni ti Iku-wolé-awo, ó máa ń ję órómodiye, eku, alángbá, ákéré àti esú; ó sì lẻ máa jęun bí ở bá n fô lọ. İtệ rẻ máa ń ga sókè diệ lórí ęka igi nígbả çęrün. Eyin kan sí méta nì ở máa ń yẻ. Ảwợ ewé àti funfun ni eyin yii máa ń nỉ șugbón ảwo pupa tóótòòtó tún máa ń wà lára çyin yii. Ó fi igbe jo igbe ológbò. Ó lẻ då rin, wộn lè rìn ní méjiméji, ní igbà miírăn, àwọn tỉ wón jọ máa ń rìn lè pé igba. Apėjá Ikúlóögùn ni Ikúlóògun-jawo-lọ nígbà tí àpėjá lkú-wolé-awo jé Ikú-wolé-awo-sákálá, ęni-ti-kò-lóbinrin-ana-re-ki-i-kú. Ikúlóògùn túmọ̀ sí pé:
- A.Ṣákálá ni ara dá
- B.Ayé ní a máa ń gbé
- C.Kò sí ìkú ní ilé awo
- D.Ikú ko ni oogun
Show answerHide answer
Answer: D Ikú ko ni oogun
- 30.Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti otelee. Ni igba kan, ní ilu Ayegbajeje, orúko inagije ni won fi máa ń pe Asá áti Awodi. İkuloogun ni wón máa ń pe Aşá, Iku-wolé-awo ni wớn si máa ń pe Awòdi. Bi wón bá féệ sảlàye nkankan nípa àwọn méjèèji wónyi, wón lè sọ pé órómodiyę, ęyę kéékėčké, eku áti alángbá ni Ikúlóògún máa ń ję. İşépé igi áti įka-igi tí kò gbó ni o fi máa ń şe ité ré si ori ęka-igi tí ó ti gbó. Eyin méta sí mrin ni ó máa ń yẻ. Àwọ funfun tí ó dàbí igbà pé a fi àwọ pupa áti sán-án-yán kùn lára bálabála ni eyin rẻ yii máa ń ní. Tí abo bá sába lórí ęyin yii dię tỉ ở bả dide, ako náà yóò sába lé e. Eyo kookan tàbí méji ni wón máa ń rin. Ikúlóògùn lẻ dúró ní ojú òfurufü fün igbả pípé láijábó. Ni ti Iku-wolé-awo, ó máa ń ję órómodiye, eku, alángbá, ákéré àti esú; ó sì lẻ máa jęun bí ở bá n fô lọ. İtệ rẻ máa ń ga sókè diệ lórí ęka igi nígbả çęrün. Eyin kan sí méta nì ở máa ń yẻ. Ảwợ ewé àti funfun ni eyin yii máa ń nỉ șugbón ảwo pupa tóótòòtó tún máa ń wà lára çyin yii. Ó fi igbe jo igbe ológbò. Ó lẻ då rin, wộn lè rìn ní méjiméji, ní igbà miírăn, àwọn tỉ wón jọ máa ń rìn lè pé igba. Apėjá Ikúlóögùn ni Ikúlóògun-jawo-lọ nígbà tí àpėjá lkú-wolé-awo jé Ikú-wolé-awo-sákálá, ęni-ti-kò-lóbinrin-ana-re-ki-i-kú. Kí ni àbùdá àdání Ikú-wòlẹ̀-awò?
- A.Wọ́n lè dá rìn
- B.Wọ́n lè jẹ eku àti òròmodiyẹ
- C.Wọ́n lè pé igba rìn pọ̀
- D.Wọ́n lè rìn ní méjìméjì
Show answerHide answer
Answer: C Wọ́n lè pé igba rìn pọ̀
- 31.Kí íṣe tó bo lọ́wọ́ rẹ, Adió jẹ́
- A.awakọ
- B.akòwé
- C.onìtajà
- D.onílù
Show answerHide answer
Answer: B akòwé
- 32.Nínu "Aṣọ funfun báláù wù mí", ọ̀rọ̀ tí a fálà sí nídìí jẹ́...
- A.àpólà orúkọ agérí
- B.ẹyàn àṣàfihàn
- C.ẹyàn alálájẹ
- D.àpónlẹ̀ ẹyàn
Show answerHide answer
Answer: A àpólà orúkọ agérí
- 33.Nínú àló "Ìjàpá àti Àdàbà jọ dá oko kan", ta ni Àdàbà fura sí pé ó ń ṣe iṣẹ́ ibi nínú oko wọn?
- A.Ọ̀lẹ
- B.Alájọbi
- C.Olódè
- D.Yannibo
Show answerHide answer
Answer: A Ọ̀lẹ
- 34.Nínú àló "Ìjàpá àti Ìyà Ẹlẹ̀pà", ta ni ó ran Ìjàpá lọ́wọ́ láti mú èrò ọkàn rẹ̀ ṣẹ?
- A.Babaláwo
- B.Ọ̀sànyìn
- C.Òkété
- D.Ọba
Show answerHide answer
Answer: A Babaláwo
- 35.Ọ̀kan lára àwọn iṣúwọn tí a fi ń ṣe àpèjúwe fáwẹ́lì ni...
- A.Afipẹ̀ àsúnsí
- B.Àfúnnupẹ̀
- C.Gíga ahon
- D.Àsénupẹ̀
Show answerHide answer
Answer: C Gíga ahon
- 36.Ọ̀kan nínú àwọn ìjọyè nínú awo Ifá ni
- A.Aláàgbàà
- B.Araba
- C.Ajànà
- D.Erelu
Show answerHide answer
Answer: B Araba
- 37.Ọkùnrin kóróbótó bí oká" jẹ́ àpẹẹrẹ
- A.ifọ̀hùn pẹ́nìyàn
- B.àfíwẹ̀ elélọ́ọ̀
- C.gbólóhùn àdógba
- D.àfíwẹ̀ tààrà
Show answerHide answer
Answer: B àfíwẹ̀ elélọ́ọ̀
- 38.Olóyè tí ó n mojútó kárákátà ní àárín ìlú nígbà àtijọ́ ni
- A.Ológun
- B.Alápinni
- C.Olúwo
- D.Pàràkòyí
Show answerHide answer
Answer: D Pàràkòyí
- 39.Ọ̀nà ibò ni ilé alàgbà Elújoba wà?
- A.Ìtaakogun
- B.Òkèrèwẹ̀
- C.Ọkọ òkè-egàn
- D.Làgèrè
Show answerHide answer
Answer: B Òkèrèwẹ̀
- 40.Oríṣìí ọ̀rọ̀-ìṣe tí ó wà nínú "Bọlá fún mi ní ìwé" ni...
- A.àsínpò
- B.ẹlẹ́là
- C.alápèpadà
- D.agbérún
Show answerHide answer
Answer: A àsínpò
- 41.Ta ni àwọn olóyè àti ará ilú bínú sí pé ó ń ṣàkóso ilú méjì pọ̀?
- A.Ọ̀rànmíyàn
- B.Ọbàwinrìn
- C.Ọlúọ̀rọ̀gbò
- D.Ọlálọmí
Show answerHide answer
Answer: A Ọ̀rànmíyàn
- 42.Ta ni Diwúrà pè ní "ojú kan èpà, oju kan erèé"?
- A.Ọmọ rẹ̀
- B.Ìyàwó-Ọmọ rẹ̀
- C.Ọkọ rẹ̀
- D.Ọmọ ọmọ rẹ̀
Show answerHide answer
Answer: D Ọmọ ọmọ rẹ̀
- 43.Ta ni ó máa ń tà ìlú lólobó ní ayé àtijọ́ bí ogun bá fẹ́ wọ ìlú lójijì?
- A.Alóre
- B.Oníbodè
- C.Balógun
- D.Àṣípa
Show answerHide answer
Answer: B Oníbodè
- 44.Ta ni olórí àgbòólé nínú àṣà ìbílẹ̀ Yorùbá?
- A.Àṣípa
- B.Baale
- C.Ọba
- D.Ìjọyè
Show answerHide answer
Answer: B Baale
Printing is turned off here to protect the question bank. Get the SmarTest app to study offline.
More free Yoruba papers
WAEC Yoruba 2008–2014 is in the app
The latest five years of each paper are free here. The SmarTest app has every year we hold, a worked explanation for each answer, and timed mock exams. It works offline.
Android, Windows, Mac and Linux